Project 211

Map showing major universities of mainland China. Universities in Project 211 are shown in pink color.

Àdàkọ:History of the People's Republic of China Project 211 (Àdàkọ:Zh) ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1995 tí ó jẹ́ iṣẹ́ àkànṣe tí óbdá lórí àwọ Fásitì tí wọ́n ṣe pàtàkì ní orílẹ̀-èdè China lábẹ́ àjọ tí ó bójútó ètò ẹ̀kọ́ lábẹ́lé. Wọ́n da iṣẹ́ àkànṣe yí sílẹ̀ láti lè fi ẹsẹ̀ iṣẹ́ ìwádí tó peregedé múlẹ̀ kí wọ́n sì wá àwọn ọ̀nà tó yanrantí fún ìdàgbà-sókè àwùjọ. Nígbà tí wọ́n kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ rẹ̀, láàrín ọdún 1996 sí ọdún 2000, iye owó tí wọ́n ṣamúlò lápapọ̀ jẹ́ bílíọ́nù méjì Dólà.[1] Nígbà tí yóò fi di ọdún 2008, orílẹ̀-èdè China ti ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì tí ó ti tó 116 nígbà tí ìdá mẹ́fà nínú àwọn ilé-ẹ̀kọ́ náà ti wà ní ipò tí wọ́n fẹ́ gan an. Project 11 mú kíkọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ ìwòsàn onípele keji àti onípele kẹta lọ sí ìlú òkèrè láti lọ kọ́ nípa ìmọ̀ náà siwájú si. Ilé-iṣẹ́ ètò ẹ̀kọ́ lábẹ́lé yí ń ri dájú wípé wọ́n ṣe àmúlò 85% àwọn ẹ̀kọ́ tí ó ṣe pàtàkì sí wọn, nígbà tí wọ́ sì wọ́ ṣe àmúlò %96 iyará ìwádí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀, wọ́n sì owó tí ó tó ìdá %70 sí ètò ìwádí ìmọ̀ ìjànlẹ̀ nìkanef>Over 10 billion yuan to be invested in "211 Project" - People's Daily Online Archived 2008-04-28 at the Wayback Machine.</ref> Gẹ́gẹ́ bí Academic Ranking of World Universities àti Times Higher Education World University Rankings ṣe Sọ, púpọ̀ nínú àwọn ilé-ẹ̀kọ́ fásitì tí Project 211 da sílẹ̀ ni wọ́n wà ní òkè jùlọ nínú àtòjọ ọgọ́rùn ún akọ́kọ́ nínú àtòjọ wọn.[2][3] Orúkọ iṣẹ́ àkànṣe yí ni wọ́ fà yọ látara gbólóhùn yí: "面向21世纪,办好100所高校 tí ó túmọ̀ sí : (Gbí gbaradì fún sẹ́túrì kọkànlélógún). Gbogbo fásitì tí wọ́ súgbá ètò yí jẹ́ ọgọ́rùn ún kan.[4] Láti ọdún 2014, Project 211 ni wọ́n ti ń ṣàtúntò sí tí wọ́n sì ti fi ìṣeẹ́ àkànṣe míràn tí wọ́n pe ní Plan 111 tí yóò ma ṣe àfikún ọgbọ́n orí àti ìwà ọmọlúàbí kún iṣẹ́ àkànṣe náà.[5][6] Nínú oṣù kẹsàn an ọdún 2017, wọ́n tún ṣe agbékalẹ̀ iṣẹ́ àkànṣe míràn tí wọ́n pe ní Double First Class University Plan was announced.[7][8] Agbékalẹ̀ tuntun yí kò fi bẹ́ẹ̀ ye àjọ tí wọ́n rí sí ipò tí àwọn fásitì kọ̀ọ̀kan wà lágbàáyé bí wọ́n ṣe lè ṣe ìgbéléwọ̀n fún wọn.[7] or replaces Project 211 and Project 985.[8]

Àtòjọ àwọn fásitì náà nìyí

Ẹkùn tí wọ́n wà Ìlú tí wọ́n wà University
Beijing (26) Beijing (26)
  • Beijing Foreign Studies University
  • Beijing Forestry University
  • Beijing Institute of Technology
  • Beijing Jiaotong University
  • Beijing Normal University
  • Beihang University
  • Beijing University of Chemical Technology
  • Beijing University of Chinese Medicine
  • Beijing University of Posts and Telecommunications
  • Beijing University of Technology
  • Central Conservatory of Music
  • Central University of Finance and Economics
  • China Agricultural University
  • China University of Geosciences (Beijing)
  • China University of Petroleum (Beijing)
  • China University of Mining and Technology (Beijing)
  • China University of Political Science and Law
  • Communication University of China
  • Minzu University of China
  • North China Electric Power University
  • Peking Union Medical College
  • Peking University
  • Renmin University of China
  • Tsinghua University
  • University of International Business and Economics
  • University of Science and Technology Beijing
Jiangsu (11) Xuzhou
  • China University of Mining and Technology
Wuxi
  • Jiangnan University
Suzhou
  • Soochow University
Nanjing (8)
  • China Pharmaceutical University
  • Hohai University
  • Nanjing Aeronautics and Astronautics University
  • Nanjing Agricultural University
  • Nanjing Normal University
  • Nanjing University
  • Nanjing University of Science and Technology
  • Southeast University
Shanghai (10) Shanghai (10)
  • Donghua University
  • East China Normal University
  • East China University of Science and Technology
  • Fudan University
  • Second Military Medical University
  • Shanghai International Studies University
  • Shanghai Jiao Tong University
  • Shanghai University
  • Shanghai University of Finance and Economics
  • Tongji University
Shaanxi (9) Xi'an (7)
  • Chang'an University
  • Fourth Military Medical University
  • Xi'an Jiaotong University
  • Xidian University
  • Shaanxi Normal University
  • Northwest University
  • Northwestern Polytechnical University
Xianyang (2)
  • Chang'an University
  • Northwest A&F University
Hubei (7) Wuhan (7)
  • China University of Geosciences (Wuhan)
  • Wuhan University
  • Huazhong University of Science and Technology
  • Wuhan University of Technology
  • Huazhong Agricultural University
  • Huazhong Normal University
  • Zhongnan University of Economics and Law
Sichuan (5) Ya'an
  • Sichuan Agricultural University
Chengdu (4)
  • Sichuan University
  • Southwest Jiaotong University
  • Southwestern University of Finance and Economics
  • University of Electronic Science and Technology of China
Tianjin (4) Tianjin (4)
  • Hebei University of Technology
  • Nankai University
  • Tianjin Medical University
  • Tianjin University
Guangdong (4) Guangzhou (4)
  • Jinan University
  • South China Normal University
  • South China University of Technology
  • Sun Yat-sen University
Hunan (4) Changsha (4)
  • Central South University
  • Hunan Normal University
  • Hunan University
  • National University of Defense Technology
Heilongjiang (4) Harbin (4)
  • Harbin Engineering University
  • Harbin Institute of Technology
  • Northeast Agricultural University
  • Northeast Forestry University
Liaoning (4) Shenyang (2)
  • Liaoning University
  • Northeastern University
Dalian (2)
  • Dalian Maritime University
  • Dalian University of Technology
Anhui (3) Hefei (3)
  • Anhui University
  • Hefei University of Technology
  • University of Science and Technology of China
Jilin (3) Yanji
  • Yanbian University
Changchun (2)
  • Jilin University
  • Northeast Normal University
Shandong (3) Qingdao (2)
  • Ocean University of China
  • China University of Petroleum (Huadong)
Jinan
  • Shandong University
Chongqing (2) Chongqing (2)
  • Chongqing University
  • Southwest University
Fujian (2) Xiamen
  • Xiamen University
Fuzhou
  • Fuzhou University
Xinjiang (2) Shihezi
  • Shihezi University
Ürümqi
  • Xinjiang University
Guizhou Guiyang
  • Guizhou University
Gansu Lanzhou
  • Lanzhou University
Hainan Haikou
  • Hainan University
Henan Zhengzhou
  • Zhengzhou University
Jiangxi Nanchang
  • Nanchang University
Qinghai Xining
  • Qinghai University
Shanxi Taiyuan
  • Taiyuan University of Technology
Yunnan Kunming
  • Yunnan University
Zhejiang Hangzhou
  • Zhejiang University
Guangxi Nanning
  • Guangxi University
Inner Mongolia Hohhot
  • Inner Mongolia University
Ningxia Yinchuan
  • Ningxia University
Tibet Lhasa
  • Tibet University

Ẹ lè wo

  • Project 985
  • 863 Program
  • Chinese university ranking (Chinese Academy of Management Science)
  • Rankings of universities in China
  • List of universities in China
  • Science and technology in China
  • C9 League
  • Excellence League
  • Double First Class University

Àwọn itọ́ka sí

  1. Li Lixu (2004). "China’s Higher Education Reform 1998-2003: A Summary". Asia Pacific Education Review V (1): 14–22. http://eri.snu.ac.kr/aper/pdf/Vol%205%20No%201%20July%202004%20PDF/02.Li%20Lixu.pdf. 
  2. "World University Rankings". Times Higher Education (THE) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-20. Retrieved 2020-05-05. 
  3. "ARWU World University Rankings 2019 | Academic Ranking of World Universities 2019 | Top 1000 universities | Shanghai Ranking - 2019". www.shanghairanking.com. Archived from the original on 2019-08-15. Retrieved 2020-05-05. 
  4. ""211工程"大事记". Ministry of Education, PRC (in Edè Ṣáínà). Archived from the original on November 22, 2016. Retrieved March 8, 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Archived copy". Archived from the original on 2017-09-09. Retrieved 2017-09-09.  Unknown parameter |url-status= ignored (help) 南京有高校称“211建设”已暂停
  6. "Archived copy". Archived from the original on 2017-09-09. Retrieved 2017-09-09.  Unknown parameter |url-status= ignored (help) 985、211取消后 仅88所高校入选“111计划”(名单)
  7. 7.0 7.1 "China to develop 42 world-class universities". People's Daily. 21 September 2017. http://en.people.cn/n3/2017/0921/c90000-9272101.html. 
  8. 8.0 8.1 "双一流大学 (shuāngyīliú dàxué): Double top university plan". Archived from the original on 2017-09-25.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)

Ìtàkùn àsopọ̀ Ìtàn

Àdàkọ:Project 211 Àdàkọ:Project 985 Àdàkọ:Education of the People's Republic of China