Ugali

Ugali,akume, amawe, ewokple, akple, àti àwọn orúkọ mìíràn, jẹ́ irú oúnjẹ kan tí a fi àgbàdo tàbí èlùbọ́ àgbàdo ṣe, ó sì jẹ́ jíjẹ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ-èdè Áfíríkà bíi: Kenya, Uganda, Tanzania, Zimbabwe, Zambia, Lesotho, Eswatini, Angola, Mozambique, Nambia, Democratic Republic of the Congo, Malawi, Botswana àti South Africa àti ní Ìwọ̀òrùn Áfíríkà bíi Togo, Ghana, Benin, Nigeria àti Cote D'Ivoire.[1] I A máa ń sèé nínú omi gbígbóná tàbí mílíkì títí tí yóò fi ki bíi òkèlè.[2] Ní ọdún 2017, wọ́n fi oúnjẹ yìí kún àwọn oúnjẹ UNESCO Representative List of the Intangible Cultural Heritage of Humanity, ọ̀kan lára àwọn oúnjẹ tuntun tí wọ́n fi ku

Àwọn Ìtọ́kasí